Ogbè Òfún Méjì
Ogbè Òfún Méjì, Ifá says: Àjìtú gb’ayéArìngìnnìgìnì gba’yìÒ jí ní kùtùkùtù r’óhun ọrọ̀ ṣ’àrí gbọ̀n lọ ọ̀run Díá fún Ọ̀rúnmìlàBaba ńt’ọ̀run bọ̀ wá’yéDíá fún Ọmọ ènìyànWọ́ n maa pín sí èrò mẹ́ ta l’áyéÀwọn tí wọ́ n wá ṣ’ayéÀwọn tí wọ́ n sìn wọ́ n wá’yéÀwọn tí wọ́ n yà wá wò’ran l’áyéGbogbo wọn ́nbọ̀ wá ṣe…