Onka Yoruba ( 1 to 100 in Yoruba)
1-Ení or ookan, okan, ọ̀kan (for numismatics or currencies like cowries or coins). 2-È jì or Eéji (for numismatics or currencies like cowries or coins). 3-Ẹta or ẹẹ́ta (for numismatics or currencies like cowries or coins, same pattern till 19). 4-Ẹrin, ẹ̀rin or ẹẹ́rin 5-Àrún or aárùn 6-Ẹfà or ẹẹ́fà 7-Èje or eéje 8-Ẹjọ, ẹ̀jọ…