Ohun to Mo nipa Eye Odidere (ayekooto)
Aiye-kooto, eye to rewa ni eye Odidere ko si ilu ti enia le de ni’le Yoruba ti enia o ni ri enikan o kere ju ti yio ni eye yi nile. Sugbon opo awon to ni eye yi nile papa ko kiyesi awon emo to wa lara eye Odidere won kan mo pe o mo…