IWULO EPO OBO FUN IWOSAN (Uses of Epo OBO for various sickness )
IWULO EPO OBO FUN IWOSAN (Uses of Epo OBO for various sickness ) 1. Ao lo enpo obo ti yio kunna. Ao da sinu omi toba loworo (togbonadie) lowuro kutukutu. Ao fi we pelu ose tobawu wa (ki owo aje matewa).2. Enpo obo lilo, pelu iyo ati eru inu aro, ao po mo ose, ao…