Oriki ile ife
ILE IFE Ife ooye lagboOmo olodo kan oteereOmo olodo kan otaaraOdo to san wereke,to san werekeTo dehinkunle oshinle to dabataTo dehinkunle adelawe to dokunOnikee ko gbodo bu muAbabaja won ko gbodo BuweOgedegede onisoboro ni yio mu omi do naa gbeSoboro mi wumi,eje ki ibi dandan maa ba alabeWon kii duro ki wa nife ooni,won kii…