Tags: iyaami

Do You know Your Problem Might not be Normal or Medical⚕️💉 ?? Why not Try 🧘‍♂️🧘 Spiritual Solution ?? | You could Seek Spiritual Solutions your issue by contacting us ⤵️

Iba survey IYAAMI ELEYE and IYAMOPO 🪬

Ìbà Ẹyẹ ṣóró-mọga ṣío-ṣíoÌbà Ẹyẹ mọ̀gà-ṣorò hiò-hiòBìrìpé ojú àláAbiyamọ ẹmọ́lóló abẹ́ òpóAbiyamọ eégún abojú kedereẸyẹ abapá-winniẸyẹ abẹsẹ̀-winniẸyẹ abìrìn àrà l’ẹ́sẹ̀ méjèèjì!!Ìbà Ẹyẹ ìṣẹ̀ǹbáyé, Ọlọ́wọ́gbọgbọrọ tíí y’ọmọ rẹ̀ l’ọ́fìn!Ìbà ẹ̀yin Ìyáàmi elékuru l’ọ́jà èjìgbòmẹkùnÀwọn ìyá mi ajíjẹ tútù má jẹ gbígbẹ, ajíjẹ tútù ma bì,Wọ́n ní ọdẹ kú moró-moró, ọdẹ kú mòro-mòro,Ṣùgbọ́n ‘Dewamiri dúró dain-dain ní…

Read More
Need Help? Chat with us